Posts

Featured Post

Husband and wife: should authority be absolute? Yorùbá ideology.

Image
Husband and wife : should authority be absolute?  According to Yorùbá context, husbands are seen as symbolic crowns of authority on the heads of their wives. Sighting from a poem by Olúyẹ́misí Adébọ̀wálé's "Ohun Ẹlẹgẹ́ ni àṣẹ" (Authority is Delicate) is a poem centered on the authority a husband has on his wife in the Yorùbá context. This idea is summed up in the following:  Akọ ladé orí aya Akọ ladé orí abo Ọkọ ni baálé lọ́ọ̀dẹ̀ Ọkọ l'Elédùà dá lápàṣẹ Aya l'Elédùà ṣe lágbáṣẹ B'Ólú bá dá ẹ lágbáṣẹ Yára fayọ̀ rẹ ara rẹ sílẹ̀ Kó o tẹríba fáṣẹ Ọba Ńlá. ( A man is the crown of a wife  A man is the crown of a woman A husband is the head of the family It is the husband the Almighty God gives the power of authority It is the wife the Almighty God makes to obey the authority If God makes you to obey authority Do humble yourself gladly And submit to the authority of the most High God..) Thus, the poet postulates that this authority should not be absolute while

Ęwààtoge: Orísirísi fìlà okùnrin ní ilè Yorùbá. Beauty&style (types of caps among Yorùbá men).

Image
A man’s dressing is considered incomplete without a cap (Fìlà). Some of these caps include, but are not limited to; Gobi (Cylindrical, which when worn may be compressed and shaped forward, sideways, or backward), Tinko, Abetí-ajá (Crest-like shape which derives its name from it's hanging flaps that resembles a dog's hanging ears. The flaps can be lowered to cover the ears in cold weather, otherwise, they are upwardly turned in normal weather), Alagbaa, Oribi, Bentigoo, Onide, and Labankada (A bigger version of the Abetí-ajá, and is worn in such a way as to reveal the contrasting color of the cloth used as underlay for the flaps).

Gírámà èdè Yorùbá: Òrò Atókùn (prepositions)

Image
 Àlàyé lórí Òrò atókùn ń gbé òwe Yorùbá léyìn pé '' bí a bójú tí a bómú, ìsàlè àgbòn làá Parí rè sí ''. Èyìí rí béè nítorí pé ohun tí a pè ní atókùn yìí jo ìsòrí Òrò ìse. Àbùdá Òrò ìse àti Òrò atókùn jora púpò láti fí so pé Òrò ìse ni, sùgbón ìsòrí Òrò tí ó dá dúró ni Òrò atókùn jé.  Àwon Òrò tí a ń pé ní atókùn ni: tí, fi, pèlú, ní, láti, fún, bá, sí. Àwon àpęęrę tó se àlàyé rè fún wa ní wònyìí. Mo fò sókè Fún ayò N ó lo sí ojà Ní àìpé. A wà Ní ibí ó. Túndé FI èrú gba ìbùkún Fájémirókun FI owó mo Olorun Àwon sójà ń TI ojú ogun Sambísa dé. Alàájì ti dé LÁTI mókà. Olóyè dé PÈLÚ ìlù àti Ariwo. Bí a bá se Akíyèsí daada, a ó ri pé ègé kan ni Òrò atókùn máa ń ní, ó máa ń bèrè pèlú kóńsónántì, ó sì máa ń gba àbò. A ó ri wí pé àwon ìrísí àti ìhùwà si rè dá gégé bí Òrò ìse.

Fact about Yorùbá people: (Suicide)

Image
Committing  suicide  is a serious abomination  in Yoruba land,  and  the  body must  not  be  lowered  down  until some  sacrifices are  performed to appease  the  gods. The  body of  such  individual will be  thrown  into  the evil forest  or outside the  town  to  avoid invoking the  anger of the gods on the land. The  family of  an  individual  that  commits suicide  will  be  tainted forever  in  the  community.

Ààbò àti ìlera: Health&protection (Traditional Medicine)

Image
Disease to the Yorùbás is seen as a disruption of our connection with the Earth. Yorubas are great believers of preventative medication. They are critical in the way they relate to modern western medicine.    In Yoruban medicine they also use dances, spiritual baths, symbolic sacrifice, song/prayer, and a change of diet to help cure the sick.  They also believe that  the only true  and complete cure can be  a change of 'consciousness' where the individual can recognize  the root  of the problem themselves and seek to eliminate it. According to elite practitioners, if we listen  to our bodies they will provide us with the preparation and appropriate knowledge we need to regain our balance with our immediate surroundings.

Ęwààtoge: Beauty&style (Agbádá clothing worn by the Yoruba)

Image
Clothing in Yoruba culture is gender sensitive. For men's' wear, they have Bùbá, Esiki and Sapara, which are regarded as Èwù Àwòtélè or under wear, while they also have Dandogo, Agbádá, Gbariye, Sulia and Oyala, which are also known as Èwù Àwòlékè / Àwòsókè or over wears. Some fashionable men may add an accessory to the Agbádá outfit in the form of a wraparound (Ìbora).Ìrùkèrè made from horse or cow tail. They also have various types of Sòkòtò or native trousers that are sown alongside the above mentioned dresses. Some of these are Kèmbè (Three-Quarter baggy pants), Gbáanu, Sóóró (Long slim / streamlined pants), Káamu & Sòkòtò Elemu.

Gírámà èdè Yorùbá: Ępón (Adverb)

Image
Èpón ni ęmèwà Òrò ìse gégé bí Èyán ti jé ęmèwà fún Òrò orúko, Ohun tí a pè ní ępón jé orísirísi wúnrèn, èyí tí ó bęęrę láti ęyo Òrò kan dé àpólà Òrò àti gbólóhùn. Nítorí náà èpón pé orísirísi: àwon tí ó jé ęyo Òrò tàbí jù bęè lo, àwon tó ń sáájú Òrò ìse, àti àwon tó ń gbęyìn Òrò ìse. Èpón ęléyo Òrò: Àwon ępón tí ó jé ęyo Òrò ni àwon Òrò bíi asògbà: ń, ti, má, máa, yóò Àti èdà won ní àyísódì: kìí, í, tíì, kò, níí. Èpón ni àwon Òrò tí a lè pé ní múùdù bí: kúkú, tètè, jàjà, mò-ón-mò, sèsè. Àwon wònyìí máa ń sáájú Òrò ìse ni. Wón lè tèlé ara won bí ìtumò bá fààyè gba ààtò béè. Fún àpęęrę: Adé máa tètè wá Adé kúkú máa tètè wá Àwon èpón kan lè tèlé Òrò ìse. Bí Òrò ìse yen bá gba àbò, àbò láti dúró ti Òrò ìse gbágbá, kí èpón àgbèyin Òrò ìse wá tèlé àkópò Òrò ìse àti àbò rè. Mo wá RÍ Mo ta epo ròbì RÍ Òrò gírámà kò tún yé mi MÓ Àwon ępón gbęyìn Òrò ìse kò pò rárá.