Gírámà èdè Yorùbá; Èyán (Adjective)
Gégé bí a ti so síwájú pé, òkan lára àwon ìsòrí Òrò lèdè Yorùbá ni Ęyán, Ó se pàtàkì kí a mò ohun tí èyán jé.
Èyán ni àtòpò Òrò ti ó bá dì mó Òrò orúko, tí ó ń fún wa ní ìmò kún ìmò nípa Òrò orúko. Fún àpęęrę
Ilé ìtajà
Ilé gíga
Ilé óúnję
Ilé oba
Ilé ìwòsàn...
Ní àtòpò Òrò méjìméjì, tí gbogbo won sì ń sòrò nípa Ilé. Irú Ilé tí a ń sòrò nípa rè dá lórí Òrò tí a fi yán an; Ę sàkíyèsí pé Èyán máa ń tèlé Òrò orúko tí ó jé kókó rè ni. A ó ma tè síwájú lósè tí ń bò. Ire ó!

Comments
Post a Comment