Gírámà èdè Yorùbá: Òrò ìse tó ju ègé kan lo) (Conjoined verb).

Gégé bí a se so lósè tó kojá wí pé, Òrò ìse jé òpómúléró nínú gbólóhùn, kìí sì ní ju ègé kan lo. Sùgbón nígbà míràn àwon Òrò ìse kòòkan a máa ní ju ègé kan lo, òpò nínú won ló jé àkànpò, yálà Òrò ìse méjì, tàbí Òrò ìse pèlú Òrò orúko : àpęęrę ni wònyìí..

Dì+mú = Dìmú
Ka+ilę =kalę
Rán+eti= rántí
Gbà+gbé= gbàgbé
Pe +olówó =polówó
Gbà +gbó = gbàgbó
Sè+ędá= sèdá
Jé +isé =jísé...
Ní sókí, Òrò ìse máa ń tèlé olùwà. Ó sì máa ń sáájú àbò àti orísirísi àfikún.

Comments

Popular posts from this blog

Gírámà èdè Yorùbá: Òrò Atókùn (prepositions)

Gírámà èdè Yorùbá; Èyán (Adjective)

Ęwààtoge: Orísirísi fìlà okùnrin ní ilè Yorùbá. Beauty&style (types of caps among Yorùbá men).