Gírámà èdè Yorùbá: Òrò ìse (verb)

Òrò ìse jé ìsòrí Òrò tí ó máa ń so ohun tí àwon Òrò orúko inú gbólóhùn se tàbí ohun tí ó selè sí Òrò orúko. Ní àtàrí pé a ò lè má rí i nínú èrò tí a pè ní gbólóhùn, àwon òmòràn nínú èdè Yorùbá ti ki ìsòrí yìí bi òpómúléró. Àfiwé yìí sì bá a mu régí. Àpęęrę Òrò ìse Ní wònyìí

Pe, wá, jókòó, tà, rà, fò, fá, rìn, jé, mu, rán, gbà, gbé, ká, fún, wó, lá, là, tì, sùn, jí, gé, kùn, bí, nù, lò, kí, gbìn.
A.b.b.l.

Akíyèsí wa ni pé Ègé kan ni Òrò ìse máa ń ní. Ogunlógò àpęęrę ló sì wà. Ibi tí Òrò ìse bá ti ni ju ègé kan lo, àlàyé rè lè wà nítòòsí.

À ó máa wo ibi tí a ti ní ju ègé kan lo lósè tí ń bò. Ire ó

Comments

Popular posts from this blog

Gírámà èdè Yorùbá: Òrò Atókùn (prepositions)

Gírámà èdè Yorùbá; Èyán (Adjective)

Ęwààtoge: Orísirísi fìlà okùnrin ní ilè Yorùbá. Beauty&style (types of caps among Yorùbá men).