Gírámà èdè Yorùbá (ìsòrí Òrò orúko)..

Gégé bí ibi tí a gbé dúró lósè tó kojá ní wí pé , a lè pín Òrò orúko sí orísirísi ònà, èyí tó ń tóka sí èèyàn, ęranko, nńkan abèmí, nńkan aláìléèmí, àfòyemò, ibi, ònkà, ipò, àti bęè bęè lo. Díè nínú Òrò orúko nípa Ìpín ìsòrí nì yìí;

Èèyàn;  Adéwálé, Àgbède, Onílù, Omoge, Olábísí,...

Ęranko;  Òyà, Àparò, Erin, Ejo, Ìnàkí, Èèrà,...

Aláìléèmí;  Òkúta, Egbò, Igi, Koríko, Ìlù,..

Àfòyemò;  Ogbón, Òótó, Ìfé, Ìjà, Àféfé,..

Ibi;     Ìsolò, Èkó, ìlorin, Odò, ibi,...

Ipò;     ìkínní, ìkejì, ìkèta,....

Ònkà;    Òkan, Èjì, Èta,....

Arópó Orúko;  Mo, O, a, Won,...

 Ìtúpalè tó gbòòrò ju èyí lo wà níta, sùgbón ohun tí ó se pàtàkì jù ni pé kí a mò ohun tí Òrò Orúko jé, yàtò sí àtúnpín ìsòrí nípa ìtumò.

Comments

Popular posts from this blog

Gírámà èdè Yorùbá: Òrò Atókùn (prepositions)

Gírámà èdè Yorùbá; Èyán (Adjective)

Ęwààtoge: Orísirísi fìlà okùnrin ní ilè Yorùbá. Beauty&style (types of caps among Yorùbá men).