Happy Birthday to ikú bàbá yèyé, Oba Adéyemí Aláàfin of òyó.

Àtàndá òòsà,
A gbó sá sá má sàá ,
irúmolè tí ń gbé'nú ààfin ,
ikú bàbá yèyé,
Aláse, èkèjì òrìsà,
 òrìsà baba Àkèé ,
òòsà Oko túnráyò,
oko Ojúolápé,
Oko Adébímpé
baba làtífátù,
Àtàndá Omo pópó,
 Oba lomo Adéyemí,
 Omo ikú, Omo àrùn!
Òkòtó aníyìkáyé olórí Oba.
Adé á pé lórí,  Àse á pé lénu, 
igba odún, ìséjú kan ni.
 E dá músò o!!!

Comments

Popular posts from this blog

Gírámà èdè Yorùbá: Òrò Atókùn (prepositions)

Gírámà èdè Yorùbá; Èyán (Adjective)

Ęwààtoge: Orísirísi fìlà okùnrin ní ilè Yorùbá. Beauty&style (types of caps among Yorùbá men).