Tia ń tia ni. (ìwà lęwà)

Yorùbá bò Wón ní;
ìwà lęwà.
Iręlę a sì máa mólá yęni.

Olorì àná, ti oba Adéyeyè Ęnìtàn Oòni ifè, fi ohun tó ní'ye lórí jùlo ní ilè Yorùbá (ìwà omolúàbí) hàn nínú Òrò tí Wón fi ránsé sáàfin sí oba àti Olorì tuntun.Òrò náà lo báyìí wí pé...

 ''it was once said that there is Nobility in Compassion,
Beauty in Empathy,and
Grace in Forgiveness.
Congratulations to the Oòni & his new bride, Shílèkùnola Naomi Morónké Oluwaseyi.
May God bless your union''.

Ohun tí èyí túmò sí ni pé;
''ìgbéga ń bę nínú fífę Ore fún Omonìkejì, Ęwà si ń bę nínú Ìfomonìyànse, àti wí pé Ore-òfę ń bę nínú Ìdáríjì.
Mó kí Oòni àti Olorì rè tuntun Shílèkùnola Naomi Morónké oluwaseyi. Èdùmàrè yóò bùkún ìgbéyàwó yín''.

Hmmm.... Ní tòótó ni wí pé Ęwà ń bę nínú ìfomonìyànse mo gbóríyìn fún @hhzaynab.

Comments

Popular posts from this blog

Gírámà èdè Yorùbá: Òrò Atókùn (prepositions)

Gírámà èdè Yorùbá; Èyán (Adjective)

Ęwààtoge: Orísirísi fìlà okùnrin ní ilè Yorùbá. Beauty&style (types of caps among Yorùbá men).