Tia n tia ni ''Ako ladé orí aya'' (A man is the crown of a wife).

Kábíyèsí oba Aláyélúwà
Òòni Adéyeyè Ęnìtàn
Babátúndé ogúnwùsì Ojaja kejí
Àgbàlagbà òrìsà
Àrólé Oòduà
Omo Òjajà fìdí òtè jálè
Omo ayí kiti ògún
Omo etíri Ògún
Ajere abojú jojo
Ká'dé ó pé lórí,
ká'se ó pé lénu kárin-kése.
@ooniadimulaife kí aręwà Olorì Shílèkùnola, Morónké Naomi @oluwaseyinaomi káàbò sáàfin,  Baba wí pé, ''I waited patiently upon the almighty the king of kings,he eventually did it in the midst of many trials. Shílèkùnola, Morónké Naomi; the greatest arsenal you can apply on this highly revered throne with many rules and regulations in the midst of undiluted traditional, heritage and culture is the ''fear of God in you'', which is the beginning of your wisdom on this throne of oduduwa.
You are welcome home my beautiful and adorable queen''.

Ohun tí oba ń so lénu kan ni wí pé ''Mo ni ìfarabalè àti sùúrù fún Elédùmarè oba àwon Oba, Ó sì se é láàárin òpòlopò ìgbìyànjú.'' baba tè síwájú láti gba Olorì ní ìmòràn wí pé,
Ìbèrù Olórun ti ń bę Lára Olorì ni wón le lò lórí àga òdùduwà torí ó kún fún òfin àti ìlànà láàárin òpòlopò àsà àti ìsèse''.
A gbà á láàdúrà wí pé Olorì Shílèkùnola, Morónké Naomi yóò bí ìsun àti ìwàlè láàfin Òòni ifè. Àse!

Kò sí ani-àní ń bę wí pé, Olorì Morónké ręwà gidi gaan ni 'ègàn ni 'hèéè' ìyàwó dùn lósìngin púpò.

Comments

Popular posts from this blog

Gírámà èdè Yorùbá: Òrò Atókùn (prepositions)

Gírámà èdè Yorùbá; Èyán (Adjective)

Ęwààtoge: Orísirísi fìlà okùnrin ní ilè Yorùbá. Beauty&style (types of caps among Yorùbá men).