Òwe Yorùbá (Yorùbá proverbs)

'' if you avoid work, you can't avoid poverty''.
Torí náà
Múra sísé òré MI.
Isé la fi ń dęni gíga.
Bí a kò bá r'éni fèhìntì,
bí òlę làárí.
Bí a kò bá r'éni gbékè lé,
a tęra m'ósé ni.
#ÒweYorùbá
#Yorùbádùn
#Wevaluemoral
#Weappreciateourculture
#Proverbmonday.

Comments

Popular posts from this blog

Gírámà èdè Yorùbá: Òrò Atókùn (prepositions)

Gírámà èdè Yorùbá; Èyán (Adjective)

Ęwààtoge: Orísirísi fìlà okùnrin ní ilè Yorùbá. Beauty&style (types of caps among Yorùbá men).