ojúlarí

OJÚLARÍ
Ojú ò ṣe fi mọ̀ ìwà ẹ̀dá,
Inú ẹ̀dá ò dàbí òde,
Bí ẹ bá rí ènìyàn,  ẹ sọ́ra fún wọn
Ẹni a ba ñ bárìn ká fura si,
Ẹni a bá fura sí ka yẹra fún wọn
Torí Ojú wa ko Ojú, ẹsẹ̀ wa ko ẹsẹ̀, Ọwọ́ wa bọwọ́
Ṣùgbọ̀n Inú wa o konú, Oníkùn ló mọ ìkà.



Comments

Popular posts from this blog

Gírámà èdè Yorùbá: Òrò Atókùn (prepositions)

Gírámà èdè Yorùbá; Èyán (Adjective)

Ęwààtoge: Orísirísi fìlà okùnrin ní ilè Yorùbá. Beauty&style (types of caps among Yorùbá men).